Винсент Вайт Oluwo Fáfémi Fátàlàbí тайны африканского оракула традиций ифá и водун (вуду)
Odù si jé eniti ti wipé ki opolopo enia kó máa ri on
ТАЙНЫ АФРИКАНСКОГО ОРАКУЛА---
- Bu sahifa navigatsiya:
- O wá lò ó ti ti ti ti o dé´lé Òrúnmilà Òrúnmilà o wá pè awon babaláwo rè O nlo rèé pè, ‘Bi a bá ko ni l´ógbón, ogbón l´eni igbón
- Awon babaláwo Òrúnmilà, nwon ni he! Nwon ni Odù ti o fé gbé ni´yàwó yii o, nwon ni, agbára kan wà l´owo rè Nwon ni, agbára náà ni ki Òrúnmilà ó rúbo silè dèé
- Nwon ni ki Òrúnmilà ó yárá rúbo´lè Nwon ni, kini ó rú silè dèé Nwon ni, k´Òrúnmilà ó ni òkété Nwon ni, ki ó si ni eku Nwon ni, ki ó si ni eja
- Òrúnmilà gbé e s´ode 137 Didé ti Odù ó dé, o bá ètùtù n´ita
- Gbogbo awon ti Odù ko léhin ni awon ebùrú O ni ki gbogbo nwon máa jeun Odù náà, ó si igbá Aragamago eiye rè silè
Ma'lumotlar bazasi mualliflik huquqi bilan himoyalangan ©fayllar.org 2024
ma'muriyatiga murojaat qiling
ma'muriyatiga murojaat qiling